ERO OMI

image

Yoruba Translation by: Mof’Oluwawo O MojolaOluwa

Bawo ni o ma n ri lara nigba ti o ba n gbiyanju ati gba elomiran la ti iwo gan wa di eni to nilo igbala, nigba ti esuo ba pa idi da to n le aja? Oju a gba ni ti fun ara eni, ara eni a ko ti o. Bee gele ni o ri lara mi ni ale ana. Nise ni mo wa ni ibi ajodun asa ati ise to larinrin kan. Nigba ti o ya, mo nilo lati gbonse. Mo lo si ile ito awon obinrin lati se bee. Nigba ti mo setan, mo si ero omi lati fowo, leyin ti mo ti fi ose sowo. Omi ko, ko yo. Mo tun si si ona miran, omi o yo. Oro ile igbonse Naijiria wa ka mi laya. Nje ki ni sise? Mo gbe igo omi mimu mi jade lati inu apamowo mi, pe ki n fi san owo mi. Igbayi gan ni arabinrin kan naa jade lati ile igbonse lati fo owo re bakan naa. Arabinrin yi je okan lara awon alejo pataki nibi ajodun naa. Bee, inu mi dun lati je olugbala re.
‘E ma ti fi ose sowo o, omi ko yo,’ mo wi fun.
O koko wo mi ni iwo aikasi
Mo tun oro mi so.
‘Ko si omi. Emi paapaa ti fi ose sowo ki n to mo’
‘Looto?’ O beere lai gbagbo. O si te ero omi.
Omi yaaa!
Oro pesi je. Mi o mo ki laawi. Mo kan wo siii!
Nigba ti oya, mo si ero omi naa.
Omi!

Mo lero pe o gbadun itan kekere alarinrin mi. Eko: Ero omi tite yato si yinyin. Kaa l’ede oyinbo nibi https://oluwapelumimojolaoluwalivingstone.wordpress.com/2017/04/19/faucet-english/?_e_pi_=7%2CPAGE_ID10%2C4415739498

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s